Ìṣe 3:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ní tòótọ́, ẹni* tí kò bá fetí sí Wòlíì yẹn ni a ó pa run pátápátá kúrò láàárín àwọn èèyàn.’+