Jẹ́nẹ́sísì 28:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ó dájú pé àtọmọdọ́mọ* rẹ yóò pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀,+ ìwọ yóò sì tàn káàkiri dé ìwọ̀ oòrùn àti ìlà oòrùn, dé àríwá àti gúúsù, ó sì dájú pé gbogbo ìdílé ayé yóò rí ìbùkún gbà*+ nípasẹ̀ ìwọ àti àtọmọdọ́mọ* rẹ.
14 Ó dájú pé àtọmọdọ́mọ* rẹ yóò pọ̀ bí erùpẹ̀ ilẹ̀,+ ìwọ yóò sì tàn káàkiri dé ìwọ̀ oòrùn àti ìlà oòrùn, dé àríwá àti gúúsù, ó sì dájú pé gbogbo ìdílé ayé yóò rí ìbùkún gbà*+ nípasẹ̀ ìwọ àti àtọmọdọ́mọ* rẹ.