-
Diutarónómì 13:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 rí i pé o yẹ ọ̀rọ̀ náà wò, kí o ṣe ìwádìí fínnífínní, kí o sì béèrè nípa rẹ̀;+ tó bá jẹ́ pé òótọ́ ni wọ́n ṣe ohun ìríra yìí láàárín rẹ,
-
-
Diutarónómì 17:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Tí wọ́n bá sọ fún ọ tàbí tí o gbọ́ nípa rẹ̀, kí o wádìí ọ̀rọ̀ náà dáadáa. Tó bá jẹ́ òótọ́ ni+ ohun ìríra yìí ṣẹlẹ̀ ní Ísírẹ́lì,
-
-
2 Kíróníkà 19:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Ó sọ fún àwọn onídàájọ́ náà pé: “Ẹ fiyè sí ohun tí ẹ̀ ń ṣe, nítorí kì í ṣe èèyàn lẹ̀ ń ṣojú fún tí ẹ bá ń dájọ́, Jèhófà ni, ó sì wà pẹ̀lú yín nígbà tí ẹ bá ń ṣe ìdájọ́.+
-