Nọ́ńbà 31:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Mósè wá rán wọn lọ, ẹgbẹ̀rún kan (1,000) látinú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan láti jagun, ó ní kí Fíníhásì+ ọmọ àlùfáà Élíásárì lọ pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun náà. Ọwọ́ rẹ̀ ni àwọn ohun èlò mímọ́ àti àwọn kàkàkí+ ogun wà.
6 Mósè wá rán wọn lọ, ẹgbẹ̀rún kan (1,000) látinú ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan láti jagun, ó ní kí Fíníhásì+ ọmọ àlùfáà Élíásárì lọ pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun náà. Ọwọ́ rẹ̀ ni àwọn ohun èlò mímọ́ àti àwọn kàkàkí+ ogun wà.