-
Àwọn Onídàájọ́ 7:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Jọ̀ọ́, kéde níṣojú gbogbo àwọn èèyàn náà báyìí, pé: ‘Kí ẹnikẹ́ni tó bá ń bẹ̀rù tí àyà rẹ̀ sì ń já pa dà sílé.’”+ Torí náà, Gídíónì dán wọn wò. Ìyẹn mú kí ẹgbẹ̀rún méjìlélógún (22,000) lára àwọn èèyàn náà pa dà sílé, ó sì ṣẹ́ ku ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000).
-