Jóṣúà 22:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun ìní pa dà lọ sí àgọ́ yín, pẹ̀lú ẹran ọ̀sìn tó pọ̀, fàdákà àti wúrà, bàbà àti irin àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ aṣọ.+ Ẹ kó ìpín yín nínú ẹrù àwọn ọ̀tá yín,+ ẹ̀yin àtàwọn arákùnrin yín.”
8 ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun ìní pa dà lọ sí àgọ́ yín, pẹ̀lú ẹran ọ̀sìn tó pọ̀, fàdákà àti wúrà, bàbà àti irin àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ aṣọ.+ Ẹ kó ìpín yín nínú ẹrù àwọn ọ̀tá yín,+ ẹ̀yin àtàwọn arákùnrin yín.”