Nọ́ńbà 35:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 “‘Ẹ má sọ ilẹ̀ tí ẹ̀ ń gbé di ẹlẹ́gbin, torí ẹ̀jẹ̀ máa ń sọ ilẹ̀+ di ẹlẹ́gbin, kò sì sí ètùtù fún ẹ̀jẹ̀ tí ẹnì kan ta sórí ilẹ̀ àyàfi ẹ̀jẹ̀ ẹni náà tó ta á sílẹ̀.+
33 “‘Ẹ má sọ ilẹ̀ tí ẹ̀ ń gbé di ẹlẹ́gbin, torí ẹ̀jẹ̀ máa ń sọ ilẹ̀+ di ẹlẹ́gbin, kò sì sí ètùtù fún ẹ̀jẹ̀ tí ẹnì kan ta sórí ilẹ̀ àyàfi ẹ̀jẹ̀ ẹni náà tó ta á sílẹ̀.+