Mátíù 7:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Torí náà, gbogbo ohun tí ẹ bá fẹ́ kí àwọn èèyàn ṣe sí yín ni kí ẹ̀yin náà máa ṣe sí wọn.+ Ní tòótọ́, ohun tí Òfin àti àwọn Wòlíì túmọ̀ sí nìyí.+
12 “Torí náà, gbogbo ohun tí ẹ bá fẹ́ kí àwọn èèyàn ṣe sí yín ni kí ẹ̀yin náà máa ṣe sí wọn.+ Ní tòótọ́, ohun tí Òfin àti àwọn Wòlíì túmọ̀ sí nìyí.+