-
Ìṣe 10:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Lọ́jọ́ kejì, bí wọ́n ṣe ń bá ìrìn àjò wọn lọ, tí wọ́n sì ń sún mọ́ ìlú náà, Pétérù lọ sórí ilé ní nǹkan bíi wákàtí kẹfà* láti gbàdúrà.
-