Léfítíkù 19:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 “‘Kí ẹ máa pa àwọn àṣẹ mi mọ́: Ẹ ò gbọ́dọ̀ mú kí oríṣi ẹran ọ̀sìn yín méjì bá ara wọn lò pọ̀. Ẹ ò gbọ́dọ̀ gbin oríṣi irúgbìn méjì sínú oko yín,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ wọ aṣọ tó ní oríṣi òwú méjì tí wọ́n hun pọ̀.+
19 “‘Kí ẹ máa pa àwọn àṣẹ mi mọ́: Ẹ ò gbọ́dọ̀ mú kí oríṣi ẹran ọ̀sìn yín méjì bá ara wọn lò pọ̀. Ẹ ò gbọ́dọ̀ gbin oríṣi irúgbìn méjì sínú oko yín,+ ẹ ò sì gbọ́dọ̀ wọ aṣọ tó ní oríṣi òwú méjì tí wọ́n hun pọ̀.+