Òwe 12:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Olódodo ń tọ́jú ẹran* ọ̀sìn rẹ̀,+Àmọ́ tí ẹni burúkú bá tiẹ̀ ṣàánú, ìkà ló máa já sí.