ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 20:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run bá Ábímélékì sọ̀rọ̀ lójú àlá ní òru, ó sọ fún un pé: “Wò ó, o ti kú tán torí obìnrin tí o mú yìí,+ ó ti lọ́kọ, ìyàwó oníyàwó+ sì ni.”

  • Ẹ́kísódù 20:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 “O ò gbọ́dọ̀ ṣe àgbèrè.+

  • Léfítíkù 20:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “‘Tí ọkùnrin kan bá bá ìyàwó ọkùnrin míì ṣe àgbèrè: Ẹ gbọ́dọ̀ pa ẹni tó bá ìyàwó ẹnì kejì rẹ̀ ṣe àgbèrè, ọkùnrin alágbèrè àti obìnrin alágbèrè náà.+

  • 1 Kọ́ríńtì 6:9, 10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Àbí ẹ ò mọ̀ pé àwọn aláìṣòdodo kò ní jogún Ìjọba Ọlọ́run ni?+ Ẹ má ṣe jẹ́ kí wọ́n ṣì yín lọ́nà.* Àwọn oníṣekúṣe,*+ àwọn abọ̀rìṣà,+ àwọn alágbèrè,+ àwọn ọkùnrin tó ń jẹ́ kí ọkùnrin bá wọn lò pọ̀,+ àwọn abẹ́yà-kan-náà-lòpọ̀,*+ 10 àwọn olè, àwọn olójúkòkòrò,+ àwọn ọ̀mùtípara,+ àwọn pẹ̀gànpẹ̀gàn* àti àwọn alọ́nilọ́wọ́gbà kò ní jogún Ìjọba Ọlọ́run.+

  • 1 Kọ́ríńtì 6:18
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 18 Ẹ máa sá fún ìṣekúṣe!*+ Gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ míì tí èèyàn lè dá wà lóde ara rẹ̀, àmọ́ ẹni tó bá ń ṣe ìṣekúṣe ń ṣẹ̀ sí ara òun fúnra rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́