-
Nọ́ńbà 35:20, 21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Tí ẹnì kan bá kórìíra ẹnì kejì rẹ̀, tó sì tì í tàbí tó ń gbèrò ibi+ sí i,* tó sì ju nǹkan lù ú, tí ẹni náà wá kú, 21 tàbí tó kórìíra ẹnì kejì rẹ̀, tó sì fi ọwọ́ lù ú, tí ẹni náà wá kú, ṣe ni kí ẹ pa ẹni tó lu ẹnì kejì rẹ̀ pa. Apààyàn ni. Ẹni tó ń gbẹ̀san ẹ̀jẹ̀ máa pa apààyàn náà tó bá ti ṣe kòńgẹ́ rẹ̀.
-