-
Jẹ́nẹ́sísì 34:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Àwọn ọmọ Jékọ́bù ń bójú tó agbo ẹran rẹ̀ nínú pápá nígbà tó gbọ́ pé ọkùnrin náà ti bá Dínà ọmọ rẹ̀ sùn. Jékọ́bù ò sì sọ nǹkan kan títí wọ́n fi dé.
-