-
Léfítíkù 21:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Tí ọkùnrin èyíkéyìí bá ní àbùkù lára, kó má ṣe sún mọ́ tòsí: ọkùnrin tó fọ́jú tàbí tó yarọ tàbí tí ojú rẹ̀ ní àbùkù* tàbí tí apá tàbí ẹsẹ̀ rẹ̀ kan gùn jù,
-
-
Àìsáyà 56:4, 5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Torí ohun tí Jèhófà sọ fún àwọn ìwẹ̀fà nìyí, àwọn tó ń pa àwọn sábáàtì mi mọ́, tí wọ́n yan ohun tí inú mi dùn sí, tí wọ́n sì rọ̀ mọ́ májẹ̀mú mi:
5 “Màá fún wọn ní ohun ìrántí àti orúkọ ní ilé mi àti lára àwọn ògiri mi,
Ohun tó dára ju àwọn ọmọkùnrin àtàwọn ọmọbìnrin.
Màá fún wọn ní orúkọ tó máa wà títí láé,
Èyí tí kò ní pa run.
-