-
Nọ́ńbà 22:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Torí náà, jọ̀ọ́ wá bá mi gégùn-ún+ fún àwọn èèyàn yìí, torí wọ́n lágbára jù mí lọ. Bóyá màá lè ṣẹ́gun wọn, kí n sì lé wọn kúrò ní ilẹ̀ náà, torí ó dá mi lójú pé ẹni tí o bá súre fún máa rí ìbùkún gbà, ègún sì máa wà lórí ẹni tí o bá gégùn-ún fún.”
-
-
Jóṣúà 24:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Bálákì ọmọ Sípórì, ọba Móábù sì dìde, ó bá Ísírẹ́lì jà. Torí náà, ó ránṣẹ́ pe Báláámù ọmọ Béórì pé kó wá gégùn-ún fún yín.+
-