-
2 Sámúẹ́lì 12:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
31 Ó kó àwọn èèyàn inú rẹ̀, ó fi wọ́n sídìí iṣẹ́ pé kí wọ́n máa fi ayùn rẹ́ òkúta, kí wọ́n máa fi àwọn ohun èlò onírin mímú àti àáké ṣiṣẹ́, kí wọ́n sì máa ṣe bíríkì. Ohun tó ṣe sí gbogbo àwọn ìlú àwọn ọmọ Ámónì nìyẹn. Níkẹyìn, Dáfídì àti gbogbo àwọn ọmọ ogun náà pa dà sí Jerúsálẹ́mù.
-