Mátíù 6:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Fún wa ní oúnjẹ òòjọ́ wa lónìí;+ Róòmù 13:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ìfẹ́ kì í ṣiṣẹ́ ibi sí ọmọnìkejì ẹni;+ torí náà, ìfẹ́ ni àkójá òfin.+