Mátíù 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ní àkókò yẹn, Jésù gba oko ọkà kọjá ní Sábáàtì. Ebi wá ń pa àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í ya àwọn erín ọkà* jẹ.+ Lúùkù 6:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ní sábáàtì kan, ó ń gba oko ọkà kọjá, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ ń ya àwọn erín ọkà* jẹ,+ wọ́n sì ń fi ọwọ́ ra á.+
12 Ní àkókò yẹn, Jésù gba oko ọkà kọjá ní Sábáàtì. Ebi wá ń pa àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í ya àwọn erín ọkà* jẹ.+
6 Ní sábáàtì kan, ó ń gba oko ọkà kọjá, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ ń ya àwọn erín ọkà* jẹ,+ wọ́n sì ń fi ọwọ́ ra á.+