Jẹ́nẹ́sísì 37:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Nígbà tí àwọn oníṣòwò tí wọ́n jẹ́ ọmọ Mídíánì+ ń kọjá lọ, wọ́n fa Jósẹ́fù jáde látinú kòtò omi náà, wọ́n sì tà á fún àwọn ọmọ Íṣímáẹ́lì ní ogún (20) ẹyọ fàdákà.+ Ni àwọn ọkùnrin yìí bá mú Jósẹ́fù lọ sí Íjíbítì. Jẹ́nẹ́sísì 40:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ṣe ni wọ́n jí mi gbé kúrò ní ilẹ̀ àwọn Hébérù,+ mi ò sì ṣe ohunkóhun níbí tó fi yẹ kí wọ́n jù mí sí ẹ̀wọ̀n.”*+
28 Nígbà tí àwọn oníṣòwò tí wọ́n jẹ́ ọmọ Mídíánì+ ń kọjá lọ, wọ́n fa Jósẹ́fù jáde látinú kòtò omi náà, wọ́n sì tà á fún àwọn ọmọ Íṣímáẹ́lì ní ogún (20) ẹyọ fàdákà.+ Ni àwọn ọkùnrin yìí bá mú Jósẹ́fù lọ sí Íjíbítì.
15 Ṣe ni wọ́n jí mi gbé kúrò ní ilẹ̀ àwọn Hébérù,+ mi ò sì ṣe ohunkóhun níbí tó fi yẹ kí wọ́n jù mí sí ẹ̀wọ̀n.”*+