-
Jeremáyà 22:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ẹni tó ń fi àìṣòdodo kọ́ ilé rẹ̀ ti gbé!
Tó ń fi àìṣẹ̀tọ́ kọ́ àwọn yàrá òkè rẹ̀,
Tó ń mú kí ọmọnìkejì rẹ̀ sìn ín láìgba nǹkan kan,
Tí kò sì fún un ní owó iṣẹ́ rẹ̀;+
-
Mátíù 20:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 “Nígbà tó di ìrọ̀lẹ́, ẹni tó ni ọgbà àjàrà náà sọ fún ọkùnrin tó fi ṣe alábòójútó pé, ‘Pe àwọn òṣìṣẹ́, kí o sì san owó iṣẹ́ wọn fún wọn,+ bẹ̀rẹ̀ látorí àwọn tó dé kẹ́yìn títí dórí àwọn ẹni àkọ́kọ́.’
-
-
-