-
2 Kíróníkà 25:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Nígbà tí ìjọba rẹ̀ ti fìdí múlẹ̀ dáadáa, ó pa àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tí wọ́n pa bàbá rẹ̀ ọba.+ 4 Àmọ́ kò pa àwọn ọmọ wọn, torí pé ó ṣe ohun tó wà lákọsílẹ̀ nínú Òfin, nínú ìwé Mósè, níbi tí Jèhófà ti pàṣẹ pé: “Àwọn bàbá kò gbọ́dọ̀ kú nítorí àwọn ọmọ, bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọmọ kò gbọ́dọ̀ kú nítorí àwọn bàbá; kí kálukú kú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ tirẹ̀.”+
-