-
Diutarónómì 26:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Kí o wá sọ níwájú Jèhófà Ọlọ́run rẹ pé, ‘Mo ti kó ìpín mímọ́ kúrò nínú ilé mi, mo sì ti fún ọmọ Léfì, àjèjì, ọmọ aláìníbaba àti opó,+ bí o ṣe pa á láṣẹ fún mi gẹ́lẹ́. Mi ò tẹ àwọn àṣẹ rẹ lójú, mi ò sì pa wọ́n tì.
-