-
Lúùkù 12:48Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
48 Àmọ́ èyí tí kò lóye, síbẹ̀ tó ṣe àwọn ohun tó fi yẹ kó jẹgba la máa nà ní ẹgba díẹ̀. Ní tòótọ́, gbogbo ẹni tí a bá fún ní púpọ̀, a máa béèrè púpọ̀ lọ́wọ́ rẹ̀, ẹni tí a bá sì yàn pé kó máa bójú tó ohun púpọ̀, ohun tó pọ̀ ju ti tẹ́lẹ̀ la máa béèrè lọ́wọ́ rẹ̀.+
-