-
1 Kọ́ríńtì 9:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Torí ó wà lákọsílẹ̀ nínú Òfin Mósè pé: “O ò gbọ́dọ̀ di ẹnu akọ màlúù nígbà tó bá ń pa ọkà.”+ Ṣé ti àwọn akọ màlúù ni Ọlọ́run ń rò ni?
-