-
Diutarónómì 6:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Rí i pé o fi àwọn ọ̀rọ̀ yìí tí mò ń pa láṣẹ fún ọ lónìí sọ́kàn,
-
-
Diutarónómì 11:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 “Rí i pé o nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ọlọ́run rẹ,+ kí o máa ṣe ojúṣe rẹ sí i, kí o sì máa pa àwọn àṣẹ rẹ̀, àwọn ìdájọ́ rẹ̀ àti àwọn òfin rẹ̀ mọ́ nígbà gbogbo.
-
-
Sáàmù 119:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Jẹ́ kí n ní òye,
Kí n lè máa tẹ̀ lé òfin rẹ,
Kí n sì máa fi gbogbo ọkàn mi pa á mọ́.
-