-
Léfítíkù 19:37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Torí náà, kí ẹ máa pa gbogbo àṣẹ mi àti gbogbo ìdájọ́ mi mọ́, kí ẹ sì máa tẹ̀ lé wọn.+ Èmi ni Jèhófà.’”