- 
	                        
            
            Diutarónómì 19:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        14 “Tí o bá gba ogún rẹ ní ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run fẹ́ fún ọ pé kó di tìrẹ, o ò gbọ́dọ̀ sún ààlà ọmọnìkejì rẹ sẹ́yìn + kúrò níbi tí àwọn baba ńlá fi sí. 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Òwe 23:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        10 Má ṣe sún ààlà àtọjọ́mọ́jọ́ sẹ́yìn,+ Má sì wọnú ilẹ̀ àwọn aláìníbaba. 
 
-