-
Ẹ́kísódù 22:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 “Ṣe ni kí ẹ pa ẹnikẹ́ni tó bá bá ẹranko sùn.+
-
-
Léfítíkù 20:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “‘Tí ọkùnrin kan bá bá ẹranko lò pọ̀, ẹ gbọ́dọ̀ pa á, kí ẹ sì pa ẹranko náà.+
-