Léfítíkù 18:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá ìyá àti ọmọbìnrin rẹ̀ lò pọ̀.+ O ò gbọ́dọ̀ mú ọmọbìnrin tí ọmọ rẹ̀ ọkùnrin bí tàbí ọmọbìnrin tí ọmọ rẹ̀ obìnrin bí kí o lè bá a lò pọ̀. Mọ̀lẹ́bí rẹ̀ tímọ́tímọ́ ni wọ́n, ìwà àìnítìjú* ni. Léfítíkù 20:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 “‘Tí ọkùnrin kan bá bá ìyà àti ọmọ lò pọ̀, ìwà àìnítìjú* ló hù.+ Ṣe ni kí ẹ fi iná sun+ òun pẹ̀lú wọn, kí ìwà àìnítìjú má bàa gbilẹ̀ láàárín yín.
17 “‘O ò gbọ́dọ̀ bá ìyá àti ọmọbìnrin rẹ̀ lò pọ̀.+ O ò gbọ́dọ̀ mú ọmọbìnrin tí ọmọ rẹ̀ ọkùnrin bí tàbí ọmọbìnrin tí ọmọ rẹ̀ obìnrin bí kí o lè bá a lò pọ̀. Mọ̀lẹ́bí rẹ̀ tímọ́tímọ́ ni wọ́n, ìwà àìnítìjú* ni.
14 “‘Tí ọkùnrin kan bá bá ìyà àti ọmọ lò pọ̀, ìwà àìnítìjú* ló hù.+ Ṣe ni kí ẹ fi iná sun+ òun pẹ̀lú wọn, kí ìwà àìnítìjú má bàa gbilẹ̀ láàárín yín.