-
Diutarónómì 26:18, 19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Jèhófà sì ti gbọ́ ohun tí o kéde lónìí pé o máa di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,*+ bó ṣe ṣèlérí fún ọ gẹ́lẹ́ àti pé o máa pa gbogbo àṣẹ rẹ̀ mọ́, 19 pé òun máa gbé ọ ga ju gbogbo orílẹ̀-èdè yòókù tó dá,+ pé òun á mú kí àwọn èèyàn máa yìn ọ́, òun sì máa mú kí o ní òkìkí àti ògo, bó ṣe ṣèlérí fún ọ gẹ́lẹ́, tí o bá fi hàn pé o jẹ́ èèyàn mímọ́ lójú Jèhófà Ọlọ́run rẹ.”+
-