Léfítíkù 26:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “‘Màá ṣojúure* sí yín, màá mú kí ẹ bímọ lémọ, kí ẹ sì di púpọ̀,+ màá sì mú májẹ̀mú tí mo bá yín dá ṣẹ.+ Sáàmù 127:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wò ó! Àwọn ọmọ* jẹ́ ogún láti ọ̀dọ̀ Jèhófà;+Èso ikùn* jẹ́ èrè.+ Sáàmù 128:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ìyàwó rẹ yóò dà bí igi àjàrà tó ń so nínú ilé rẹ;+Àwọn ọmọ rẹ yóò dà bí àwọn ẹ̀ka tó ṣẹ̀ṣẹ̀ yọ lára igi ólífì, wọ́n á yí tábìlì rẹ ká.
9 “‘Màá ṣojúure* sí yín, màá mú kí ẹ bímọ lémọ, kí ẹ sì di púpọ̀,+ màá sì mú májẹ̀mú tí mo bá yín dá ṣẹ.+
3 Ìyàwó rẹ yóò dà bí igi àjàrà tó ń so nínú ilé rẹ;+Àwọn ọmọ rẹ yóò dà bí àwọn ẹ̀ka tó ṣẹ̀ṣẹ̀ yọ lára igi ólífì, wọ́n á yí tábìlì rẹ ká.