- 
	                        
            
            Ẹ́kísódù 4:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        11 Jèhófà sọ fún un pé: “Ta ló fún èèyàn ní ẹnu, ta ló sì ń mú kó má lè sọ̀rọ̀, kó ya adití, kó ríran kedere tàbí kó fọ́jú? Ǹjẹ́ kì í ṣe èmi Jèhófà ni? 
 
-