-
Diutarónómì 28:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 “Àmọ́ tí o ò bá pa gbogbo àṣẹ àti òfin Jèhófà Ọlọ́run rẹ mọ́, èyí tí mò ń pa láṣẹ fún ọ lónìí, láti fi hàn pé ò ń fetí sí ohùn rẹ̀, gbogbo ègún yìí máa wá sórí rẹ, ó sì máa bá ọ:+
-
-
Diutarónómì 29:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Jèhófà wá bínú gidigidi sí ilẹ̀ náà, ó sì mú gbogbo ègún tí wọ́n kọ sínú ìwé yìí wá sórí rẹ̀.+
-