Jeremáyà 44:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Wò ó, ojú mi wà lára wọn fún àjálù, kì í ṣe fún ohun rere;+ gbogbo àwọn ọkùnrin Júdà tó wà ní ilẹ̀ Íjíbítì ni idà àti ìyàn yóò pa, títí wọn kò fi ní sí mọ́.+
27 Wò ó, ojú mi wà lára wọn fún àjálù, kì í ṣe fún ohun rere;+ gbogbo àwọn ọkùnrin Júdà tó wà ní ilẹ̀ Íjíbítì ni idà àti ìyàn yóò pa, títí wọn kò fi ní sí mọ́.+