Diutarónómì 11:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Kí ẹ rí i pé ẹ ò jẹ́ kí ọkàn yín fà sí àwọn ọlọ́run míì, kí ẹ wá yà bàrá lọ sìn wọ́n tàbí kí ẹ forí balẹ̀ fún wọn.+ Hébérù 3:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹ̀yin ará, ẹ ṣọ́ra, kí ẹnì kankan nínú yín má lọ ní ọkàn burúkú tí kò ní ìgbàgbọ́, tí á mú kó fi Ọlọ́run alààyè sílẹ̀;+
16 Kí ẹ rí i pé ẹ ò jẹ́ kí ọkàn yín fà sí àwọn ọlọ́run míì, kí ẹ wá yà bàrá lọ sìn wọ́n tàbí kí ẹ forí balẹ̀ fún wọn.+
12 Ẹ̀yin ará, ẹ ṣọ́ra, kí ẹnì kankan nínú yín má lọ ní ọkàn burúkú tí kò ní ìgbàgbọ́, tí á mú kó fi Ọlọ́run alààyè sílẹ̀;+