Jeremáyà 31:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Kò ní dà bíi májẹ̀mú tí mo bá àwọn baba ńlá wọn dá ní ọjọ́ tí mo dì wọ́n lọ́wọ́ mú láti mú wọn kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ ‘májẹ̀mú mi tí wọ́n dà,+ bó tilẹ̀ jẹ́ pé èmi ni ọ̀gá wọn tòótọ́,’* ni Jèhófà wí.”
32 Kò ní dà bíi májẹ̀mú tí mo bá àwọn baba ńlá wọn dá ní ọjọ́ tí mo dì wọ́n lọ́wọ́ mú láti mú wọn kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì,+ ‘májẹ̀mú mi tí wọ́n dà,+ bó tilẹ̀ jẹ́ pé èmi ni ọ̀gá wọn tòótọ́,’* ni Jèhófà wí.”