-
Sáàmù 78:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ó gbé ìránnilétí kan kalẹ̀ ní Jékọ́bù,
Ó sì ṣe òfin ní Ísírẹ́lì;
Ó pa àṣẹ fún àwọn baba ńlá wa
Pé kí wọ́n jẹ́ kí àwọn ọmọ wọn mọ àwọn nǹkan yìí,+
-