-
Àwọn Onídàájọ́ 13:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Obìnrin náà wá lọ sọ fún ọkọ rẹ̀ pé: “Èèyàn Ọlọ́run tòótọ́ kan wá sọ́dọ̀ mi, ó rí bí áńgẹ́lì Ọlọ́run tòótọ́, ó ń bani lẹ́rù gidigidi. Mi ò béèrè ibi tó ti wá lọ́wọ́ rẹ̀, kò sì sọ orúkọ rẹ̀ fún mi.+
-
-
Ìṣe 1:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Bí wọ́n ṣe tẹjú mọ́ sánmà nígbà tó ń lọ, lójijì ọkùnrin méjì tó wọ aṣọ funfun+ dúró lẹ́gbẹ̀ẹ́ wọn,
-