-
Ẹ́kísódù 3:4, 5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Nígbà tí Jèhófà rí i pé ó lọ wò ó, Ọlọ́run pè é látinú igi ẹlẹ́gùn-ún náà pé: “Mósè! Mósè!” Ó dáhùn pé: “Èmi nìyí.” 5 Ó wá sọ pé: “Má ṣe sún mọ́ ibí yìí. Bọ́ bàtà ẹsẹ̀ rẹ, torí ilẹ̀ mímọ́ ni ibi tí o dúró sí.”
-