-
Jóṣúà 6:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Jẹ́ kí àlùfáà méje mú ìwo àgbò méje dání níwájú Àpótí náà. Àmọ́ ní ọjọ́ keje, kí ẹ yan yí ìlú náà ká lẹ́ẹ̀méje, kí àwọn àlùfáà sì fun àwọn ìwo náà.+
-