-
Diutarónómì 29:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Torí náà, ẹ máa pa àwọn ọ̀rọ̀ májẹ̀mú yìí mọ́, kí ẹ sì máa tẹ̀ lé wọn, kí gbogbo ohun tí ẹ bá ń ṣe lè yọrí sí rere.+