Jóṣúà 22:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Nígbà tí Ákánì+ ọmọ Síírà hùwà àìṣòótọ́ lórí ọ̀rọ̀ ohun tí a máa pa run, ṣebí gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ni Ọlọ́run bínú sí?+ Òun nìkan kọ́ ló kú torí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.’”+ 1 Kíróníkà 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ọmọ* Kámì ni Ákárì,* ẹni tó mú àjálù* bá Ísírẹ́lì+ nígbà tó hùwà àìṣòótọ́ torí ó mú ohun tí wọ́n fẹ́ pa run.+
20 Nígbà tí Ákánì+ ọmọ Síírà hùwà àìṣòótọ́ lórí ọ̀rọ̀ ohun tí a máa pa run, ṣebí gbogbo àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ni Ọlọ́run bínú sí?+ Òun nìkan kọ́ ló kú torí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀.’”+
7 Ọmọ* Kámì ni Ákárì,* ẹni tó mú àjálù* bá Ísírẹ́lì+ nígbà tó hùwà àìṣòótọ́ torí ó mú ohun tí wọ́n fẹ́ pa run.+