Jóṣúà 1:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ṣe la máa pa ẹnikẹ́ni tó bá tàpá sí àṣẹ rẹ, tí kò sì tẹ̀ lé gbogbo ohun tí o bá pa láṣẹ fún un.+ Ìwọ ṣáà ti jẹ́ onígboyà àti alágbára.”+ Jóṣúà 7:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Jóṣúà sọ pé: “Kí ló dé tí o fa àjálù* bá wa?+ Jèhófà máa mú àjálù bá ọ lónìí.” Ni gbogbo Ísírẹ́lì bá sọ ọ́ lókùúta,+ lẹ́yìn náà, wọ́n dáná sun wọ́n.+ Bí wọ́n ṣe sọ gbogbo wọn lókùúta nìyẹn.
18 Ṣe la máa pa ẹnikẹ́ni tó bá tàpá sí àṣẹ rẹ, tí kò sì tẹ̀ lé gbogbo ohun tí o bá pa láṣẹ fún un.+ Ìwọ ṣáà ti jẹ́ onígboyà àti alágbára.”+
25 Jóṣúà sọ pé: “Kí ló dé tí o fa àjálù* bá wa?+ Jèhófà máa mú àjálù bá ọ lónìí.” Ni gbogbo Ísírẹ́lì bá sọ ọ́ lókùúta,+ lẹ́yìn náà, wọ́n dáná sun wọ́n.+ Bí wọ́n ṣe sọ gbogbo wọn lókùúta nìyẹn.