1 Kíróníkà 22:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wàá sì ṣàṣeyọrí tí o bá rí i pé o tẹ̀ lé àwọn ìlànà+ àti ìdájọ́ tí Jèhófà ní kí Mósè fún Ísírẹ́lì.+ Jẹ́ onígboyà àti alágbára. Má bẹ̀rù, má sì jáyà.+
13 Wàá sì ṣàṣeyọrí tí o bá rí i pé o tẹ̀ lé àwọn ìlànà+ àti ìdájọ́ tí Jèhófà ní kí Mósè fún Ísírẹ́lì.+ Jẹ́ onígboyà àti alágbára. Má bẹ̀rù, má sì jáyà.+