Jóṣúà 7:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Àwọn ọkùnrin Áì pa ọkùnrin mẹ́rìndínlógójì (36), wọ́n sì lé wọn láti ẹ̀yìn ẹnubodè ìlú títí dé Ṣébárímù,* wọ́n ń pa wọ́n ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè. Jìnnìjìnnì bá àwọn èèyàn náà, ọkàn* wọn sì domi.
5 Àwọn ọkùnrin Áì pa ọkùnrin mẹ́rìndínlógójì (36), wọ́n sì lé wọn láti ẹ̀yìn ẹnubodè ìlú títí dé Ṣébárímù,* wọ́n ń pa wọ́n ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè. Jìnnìjìnnì bá àwọn èèyàn náà, ọkàn* wọn sì domi.