-
Jóṣúà 8:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Tí wọ́n bá ti tẹ̀ lé wa, a máa tàn wọ́n jìnnà sí ìlú náà, torí wọ́n á sọ pé, ‘Wọ́n ń sá fún wa bíi ti tẹ́lẹ̀.’+ A sì máa sá fún wọn.
-