Diutarónómì 28:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Gbogbo ìbùkún yìí máa jẹ́ tìrẹ, ó sì máa bá ọ,+ torí pé ò ń fetí sí ohùn Jèhófà Ọlọ́run rẹ: