10 “Gbogbo yín lẹ dúró níwájú Jèhófà Ọlọ́run yín lónìí, àwọn olórí ẹ̀yà yín, àwọn àgbààgbà yín, àwọn aṣojú yín, gbogbo ọkùnrin Ísírẹ́lì, 11 àwọn ọmọ yín, àwọn ìyàwó yín,+ àwọn àjèjì tó wà nínú ibùdó yín,+ látorí ẹni tó ń bá yín ṣẹ́gi dórí ẹni tó ń bá yín fa omi.