-
Jóṣúà 9:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Wọ́n wá lọ bá Jóṣúà níbi tí Ísírẹ́lì pàgọ́ sí ní Gílígálì,+ wọ́n sì sọ fún òun àtàwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì pé: “Ọ̀nà jíjìn la ti wá. Ẹ wá bá wa dá májẹ̀mú.”
-